Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

ILÉ ÌṢỌ́ (Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́) June 2016

Àwọn àpilẹ̀kọ tá a máa kẹ́kọ̀ọ́ láti August 1 sí 28, 2016 ló wà nínú Ilé Ìṣọ́ yìí.

Jèhófà “Bìkítà fún Yín”

Kí ló lè mú kó dá ẹ lójú pé Ọlọ́run nífẹ̀ẹ́ rẹ? Ronú nípa àwọn ohun tó wà nínú àpilẹ̀kọ yìí.

Mọyì Jèhófà Tó Jẹ́ Amọ̀kòkò Wa

Ọlọ́run ni Amọ̀kòkò Ńlá wa, àmọ́ báwo ló ṣe ń pinnu àwọn tó máa mọ? Kí ló dé tó fi ń mọ wọ́n? Báwo ló ṣe ń mọ wọ́n?

Ṣé Wàá Jẹ́ Kí Amọ̀kòkò Ńlá Náà Mọ Ẹ́?

Àwọn ànímọ́ wo ló yẹ kó o ní táá jẹ́ kó o di ẹni tí Ọlọ́run lè mọ?

Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé

Nínú ìran Ísíkíẹ́lì, ta ni ọkùnrin tó ní ìwo yíǹkì akọ̀wé àtàwọn ọkùnrin mẹ́fà tí wọ́n ní ohun ìjà tó lè fọ́ nǹkan túútúú ń ṣàpẹẹrẹ?

“Jèhófà Ọlọ́run Wa, Jèhófà Kan Ṣoṣo Ni”

Báwo ni Jèhófà ṣe jẹ́ Ọlọ́run kan ṣoṣo? Báwo la sì ṣe lè fi hàn pé ọ̀kan ṣoṣo ni?

Má Ṣe Jẹ́ Kí Àṣìṣe Àwọn Míì Mú Ẹ Kọsẹ̀

Láyé àtijọ́, àwọn tó fòótọ́ ọkàn sin Ọlọ́run sọ tàbí ṣe ohun tó múnú bí àwọn míì. Kí la lè rí kọ́ lára àwọn tí Bíbélì sọ̀rọ̀ nípa wọn yẹn?

Ìwà Rere Tó Ṣeyebíye Ju Dáyámọ́ǹdì Lọ

Àṣeyọrí ńlá lèèyàn ṣe téèyàn bá jẹ́ olóòótọ́.

Ǹjẹ́ O Rántí?

Ṣé o ti ka àwọn ẹ̀dà Ilé Ìṣọ́ tó jáde lẹ́nu àìpẹ́ yìí? Wò ó bóyá wà á lè dáhùn àwọn ìdáhùn yìí.