Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

ILÉ ÌṢỌ́ (Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́) July 2017

Àwọn àpilẹ̀kọ tá a máa kẹ́kọ̀ọ́ láti August 28 sí September 24, 2017, ló wà nínú Ilé Ìṣọ́ yìí.

Wọ́n Yọ̀ǹda Ara Wọn Tinútinú​​—Ní Tọ́kì

Lọ́dún 2014, wọ́n ṣe àkànṣe ìwàásù kan ní Tọ́kì. Kí nìdí tí wọ́n fi ṣe àkànṣe ìwàásù náà? Kí ló sì yọrí sí?

Bá A Ṣe Lè Ní Ọrọ̀ Tòótọ́

Báwo la ṣe lè fi àwọn ohun ìní wa bá Jèhófà dọ́rẹ̀ẹ́?

‘Ẹ Máa Sunkún Pẹ̀lú Àwọn Tí Ń Sunkún’

Báwo lẹnì kan ṣe lè rí ìtùnú tí ẹnì kan tó fẹ́ràn bá kú? Báwo la ṣe lè ran irú ẹni bẹ́ẹ̀ lọ́wọ́?

Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Ká Máa Yin Jèhófà?

Sáàmù 147 jẹ́ ká rí ìdí tó fi yẹ ká mọyì Ẹlẹ́dàá wa ká sì máa yìn ín.

Jèhófà Máa Jẹ́ Kí Àwọn Ìpinnu Rẹ Yọrí Sí Rere

Àwọn ọ̀dọ́ gbọ́dọ̀ pinnu ohun tí wọ́n á fayé wọn ṣe, àmọ́ kì í rọrùn nígbà mí ì. Jèhófà máa bùkún àwọn tó bá ń wá ìtọ́sọ́nà rẹ̀.

Má Ṣe Jẹ́ Kí Sátánì Tàn Ẹ́ Jẹ

Sátánì ti gbówọ́ nínú kó máa tan àwọn èèyàn jẹ. Kí lo lè ṣe tí kò fi ní rí ẹ mú?

Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé

Ṣé ó yẹ kí Kristẹni kan ní ìbọn torí kó lè dáàbò bo ara rẹ̀ lọ́wọ́ àwọn olubi?