Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

ILÉ ÌṢỌ́ (Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́) July 2016

Àwọn àpilẹ̀kọ tá a máa kẹ́kọ̀ọ́ láti August 29 sí September 25, 2016 ló wà nínú Ilé Ìṣọ́ yìí.

Wọ́n Yọ̀ǹda Ara Wọn Tinútinú—Ní Gánà

Ìṣòro táwọn tó lọ sìn níbi tí àìní wà máa ń pọ̀. Àmọ́ èyí kì í tó nǹkan kan tá a bá fi wé àwọn ìbùkún tí wọ́n máa ń rí.

Kí Nìdí Tá A Fi Gbọ́dọ̀ Máa Ṣọ́nà?

Àwọn nǹkan mẹ́ta wo ló lè mú ká dẹra nù tá ò bá ṣọ́ra.

A Mọyì Inú Rere Àìlẹ́tọ̀ọ́sí Tí Ọlọ́run Ń Fi Hàn sí Wa

Ọ̀nà tó ga jù lo wo ni Ọlọ́run gbà fi inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí hàn sí wa?

Ẹ Jẹ́ Kí Aráyé Gbọ́ Ìhìn Rere Nípa Inú Rere Àìlẹ́tọ̀ọ́sí Ọlọ́run

Báwo ni “ìhìn rere Ìjọba Ọlọ́run” ṣe mú ká mọ̀ nípa inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí Ọlọ́run?

Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé

Ìwé Ìsíkíẹ́lì orí 37 sọ pé a so ọ̀pá méjì pa pọ̀ di ọ̀kan. Kí nìyẹn túmọ̀ sí?