Ó ń tọ́ka sí Ilé Ìṣọ́ tí àpilẹ̀kọ kọ̀ọ̀kan ti jáde

ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́

 • A Mọyì Inú Rere Àìlẹ́tọ̀ọ́sí Tí Ọlọ́run Ń Fi Hàn sí Wa, July

 • A Mú Wọn Jáde Kúrò Nínú Òkùnkùn, Nov.

 • À Ń Láyọ̀ Bá A Ṣe Ń Bá Ọlọ́run Ṣiṣẹ́, Jan.

 • “Àwa Yóò Bá Yín Lọ” Jan.

 • Báwo Lo Ṣe Lè Pa Kún Ìṣọ̀kan Tó Wà Láàárín Àwa Kristẹni? Mar.

 • Báwo Lo Ṣe Máa Ń Ṣèpinnu? May

 • Bó O Ṣe Lè Mú Kó Túbọ̀ Dá Ẹ Lójú Pé Ìlérí Ọlọ́run Máa Ṣẹ, Oct.

 • Ẹ Jẹ́ Kí Aráyé Gbọ́ Ìhìn Rere Nípa Inú Rere Àìlẹ́tọ̀ọ́sí Ọlọ́run, July

 • “Ẹ Jẹ́ Kí Ìfaradà Ṣe Iṣẹ́ Rẹ̀ Pé Pérépéré,” Apr.

 • “Ẹ Jẹ́ Kí Ìfẹ́ Ará Tí Ẹ Ní Máa Bá A Lọ”! Jan.

 • “Ẹ Lọ, Kí Ẹ sì Máa Sọ Àwọn Ènìyàn Gbogbo Orílẹ̀-Èdè Di Ọmọ Ẹ̀yìn,” May

 • “Ẹ Má Gbàgbé Aájò Àlejò,” Oct.

 • Ẹ Máa Fìfẹ́ Yanjú Aáwọ̀, May

 • ‘Ẹ Máa Gba Ara Yín Níyànjú Lẹ́nì Kìíní-Kejì Lójoojúmọ́,’ Nov.

 • Ẹ̀mí Ń Jẹ́rìí Pẹ̀lú Ẹ̀mí Wa, Jan.

 • Ẹ̀yin Òbí, Ẹ Ṣe Ohun Táá Jẹ́ Káwọn Ọmọ Yín Nígbàgbọ́, Sept.

 • Ẹ̀yin Ọ̀dọ́, Ẹ Mú Kí Ìgbàgbọ́ Yín Túbọ̀ Lágbára, Sept.

 • Ẹ̀yin Ọ̀dọ́—Báwo Lẹ Ṣe Lè Múra Sílẹ̀ fún Ìrìbọmi? Mar.

 • Ẹ̀yin Ọ̀dọ́—Ṣé Ẹ Ti Múra Tán Láti Ṣe Ìrìbọmi? Mar.

 • “Gbígbé Èrò Inú Ka Ẹ̀mí Túmọ̀ Sí Ìyè àti Àlàáfíà,” Dec.

 • Jèhófà Máa Ń Sẹ̀san fún Àwọn Tó Ń Fi Taratara Wá A, Dec.

 • Jèhófà Ń Tọ́ Wa Sọ́nà Ká Lè Jogún Ìyè, Mar.

 • “Jèhófà Ọlọ́run Wa, Jèhófà Kan Ṣoṣo Ni,” June

 • Jèhófà Pè É Ní “Ọ̀rẹ́ Mi,” Feb.

 • Jẹ́ Adúróṣinṣin sí Jèhófà, Feb.

 • Jẹ́ Kí ‘Ẹ̀bùn Ọ̀fẹ́ Aláìṣeé-Ṣàpèjúwe’ Ti Ọlọ́run Mú Ẹ Lọ́ranyàn, Jan.

 • Kẹ́kọ̀ọ́ Lára Àwọn Ìránṣẹ́ Jèhófà Tó Jẹ́ Adúróṣinṣin, Feb.

 • Kí Nìdí Tá A Fi Gbọ́dọ̀ Máa Ṣọ́nà? July

 • Kí Nìdí Tí Ọlọ́run Fi Ṣètò Ìgbéyàwó? Aug.

 • Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Ká Máa Dá Àwọn Míì Lẹ́kọ̀ọ́? Aug.

 • Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Ká Máa Pé Jọ Láti Jọ́sìn? Apr.

 • Kó Gbogbo Àníyàn Rẹ Lé Jèhófà, Dec.

 • Má Ṣe Dá Sí Ọ̀rọ̀ Òṣèlú Tàbí Ogun, Apr.

 • Má Ṣe Jẹ́ Kí Àṣìṣe Àwọn Míì Mú Ẹ Kọsẹ̀, June

 • Má Ṣe Jẹ́ Kí Ìgbàgbọ́ Rẹ Jó Rẹ̀yìn Tó O Bá Ń Sìn Nílẹ̀ Àjèjì, Oct.

 • ‘Má Ṣe Jẹ́ Kí Ọwọ́ Rẹ Rọ Jọwọrọ,’ Sept.

 • Máa Jà Fitafita Kó O Lè Rí Ìbùkún Jèhófà, Sept.

 • Máa Jẹ Oúnjẹ Tẹ̀mí Tí Jèhófà Ń Pèsè fún Wa Lájẹyó, May

 • Máa Lo Ìgbàgbọ́ Nínú Àwọn Ìlérí Jèhófà, Oct.

 • Máa Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Àwọn Ọ̀rẹ́ Jèhófà, Feb.

 • Máa Wá Ìjọba Ọlọ́run, Má Ṣe Wá Àwọn Nǹkan, July

 • Mọyì Jèhófà Tó Jẹ́ Amọ̀kòkò Wa, June

 • Ǹjẹ́ Bíbélì Ṣì Ń Yí Ìgbésí Ayé Rẹ Pa Dà? May

 • Ǹjẹ́ Ìmúra Rẹ Ń Fògo fún Ọlọ́run? Sept.

 • Ǹjẹ́ O Lè Fi Kún Ohun Tó Ò Ń Ṣe Nínú Ìjọsìn Ọlọ́run? Aug.

 • Ohun Táá Jẹ́ Kí Tọkọtaya Bára Wọn Kalẹ́, Aug.

 • Ọlọ́run Dá Wa Sílẹ̀ Nípasẹ̀ Inú Rere Àìlẹ́tọ̀ọ́sí, Dec.

 • Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run Ń Mú Ká Wà Létòletò, Nov.

 • Ṣé Ọwọ́ Pàtàkì Lo Fi Ń Mú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run? Nov.

 • Ṣé Wàá Jẹ́ Kí Amọ̀kòkò Ńlá Náà Mọ Ẹ́? June

 • Tá A Bá Jẹ́ Olóòótọ́, A Máa Rí Ojúure Ọlọ́run, Apr.

 • Wọ́n Bọ́ Lọ́wọ́ Ìsìn Èké, Nov

ÀWỌN ẸLẸ́RÌÍ JÈHÓFÀ

 • “Àwọn Tá A Fa Iṣẹ́ Náà Lé Lọ́wọ́” (Àpéjọ Cedar Point, Ohio, lórílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà), May

 • “Ẹ Jára Mọ́ṣẹ́, Ẹ̀yin Akéde Ìjọba Ọlọ́run Tó Wà Nílẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì!!” (1937), Nov.

 • “Iṣẹ́ Ìwàásù Ń Sèso Rere, Ó sì Ń Fògo fún Jèhófà” (Jámánì, Ogun Àgbáyé Kìíní), Aug.

 • “Iṣẹ́ Náà Pọ̀” (ọrẹ), Nov.

 • Jẹ́ Kí Jèhófà Máa Tọ́ Ẹ Sọ́nà (àwọn ìrírí), Sept.

 • Yọ̀ǹda Ara Wọn ní Gánà, July

BÍBÉLÌ

 • Bí Ọlọ́run Ṣé Pa Á Mọ́, No. 4

 • Lefèvre d’Étaples (atúmọ̀ èdè), No. 6

 • Orí àti Ẹsẹ, No. 2

BÍBÉLÌ MÁA Ń YÍ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀWỌN ÈÈYÀN PA DÀ

 • Ayọ̀ àti Ìbàlẹ̀ Ọkàn fún Ọdún Kan Péré (A. Broggio), No. 1

 • Inú Mi Kì Í Dùn, Mo Sì Máa Ń Hùwà Ìpáǹle (A. De la Fuente), No. 5

 • Mo Kọ́ Láti Bọ̀wọ̀ fún Àwọn Obìnrin (J. Ehrenbogen), No. 3

 • Mo Ṣàṣìṣe Lọ́pọ̀ Ìgbà (J. Mutke), No. 4

ÌBÉÈRÈ LÁTI ỌWỌ́ ÀWỌN ÒǸKÀWÉ

 • Adágún omi Bẹtisátà “dà rú” (Jo 5:7), May

 • Bí àwọn ará ṣe lè fi ayọ̀ wọn hàn nígbà tí wọ́n bá gba ẹnì kan pa dà, May

 • Ìgbà wo ni Bábílónì Ńlá mú àwọn èèyàn Ọlọ́run nígbèkùn? Mar.

 • Kí ló dé táwọn ọ̀tá Jésù fi ranrí mọ́ ọ̀rọ̀ fífọ ọwọ́? (Mk 7:5), Aug.

 • Kí ni “ọ̀rọ̀ Ọlọ́run”? (Heb 4:12), Sept.

 • Ọkùnrin tó ní ìwo yíǹkì akọ̀wé àtàwọn ọkùnrin mẹ́fà tí wọ́n ní ohun ìjà (Isk 9:2), June

 • Pípa ọ̀pá méjì pa pọ̀ di ọ̀kan (Isk 37), July

 • Ṣé Sátánì mú Jésù lọ sí tẹ́ńpìlì? (Mt 4:5; Lk 4:9), Mar.

 • Ṣó tọ́ ká fún òṣìṣẹ́ ìjọba kan ní owó tàbí ẹ̀bùn, May

ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI ÀNÍMỌ́ KRISTẸNI

 • “Fi Ìṣọ́ Ṣọ́ Ọgbọ́n Tí Ó Gbéṣẹ́,” Oct.

 • Gbèjà Ìhìn Rere Níwájú Àwọn Aláṣẹ, Sept.

 • Ìwà Tútù—Ohun Tó Bọ́gbọ́n Mu, Dec.

 • Jọ́sìn ní Ojúbọ? No. 2

 • Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Ká Jẹ́ Olóòótọ́? No. 1

 • Má Ṣe Máa Ṣàníyàn, No. 1

 • Máa Fayọ̀ Sin Jèhófà, Feb.

 • Ran Ìjọ Rẹ Lọ́wọ́, Mar.

 • Sàn Ju Góòlù (ọgbọ́n Ọlọ́run), Aug.

 • Ṣé Bí Ìrì Ni Iṣẹ́ Ìwàásù Rẹ Rí? Apr.

 • Ṣeyebíye Ju Dáyámọ́ǹdì (jíjẹ́ olóòótọ́), June

 • Tó Bá Ń Ṣe Ẹ́ Bíi Pé O Kò Já Mọ́ Nǹkan Kan, No. 1

ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ

 • Àwọn Obìnrin Ajẹ́jẹ̀ẹ́ Ìnìkàngbé Di Ìránṣẹ́ Jèhófà (F. and A. Fernández), Apr.

 • Jèhófà Ti Jẹ́ Kí N Ṣàṣeyọrí (C. Robison), Feb.

 • Mo Di “Ohun Gbogbo fún Ènìyàn Gbogbo” (D. Hopkinson), Dec.

 • Mo Kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Bó Tilẹ̀ Jẹ́ Pé Mi Ò Ní Apá (B. Merten), No. 6

 • Mo Láyọ̀ Pé Mò Ń Lo Ara Mi Lẹ́nu Iṣẹ́ Ọlọ́run (R. Parkin), Aug.

 • Mo Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Tó Dáa (T. McLain), Oct.

JÈHÓFÀ

 • “Bìkítà fún Yín,” June

 • “Má Fòyà. Èmi Fúnra Mi Yóò Ràn Ọ́ Lọ́wọ́,” July

 • Orúkọ, No. 3

JÉSÙ KRISTI

 • Bàbá Jósẹ́fù, No. 3

 • Hùwà Sáwọn Adẹ́tẹ̀, No. 4

 • Ìdí Tó Fi Jìyà Tó sì Kú? No. 2

Ọ̀KAN-Ò-JỌ̀KAN

 • Àfiwé Tó Dára Jù Lọ (fi ìgbàgbọ́ wéra pẹ̀lú Bíbélì), No. 4

 • Agbára Táwọn Róòmù Fún Ilé Ẹjọ́ Àwọn Júù, Oct.

 • Àkájọ Ìwé Láyé Ìgbà Tí Wọ́n Ń Kọ Bíbélì, No. 1

 • Aṣọ àti Aró Láyé Ìgbà Tí Wọ́n Ń Kọ Bíbélì, No. 3

 • Àwọn olórí àlùfáà tá a mẹ́nu kàn nínú Bíbélì, No. 1

 • Ẹ̀kọ́ Tá A Rí Kọ́ Lára Àwọn Ẹyẹ, No. 6

 • Gbígba Ìkìlọ̀, No. 2

 • Ibo Lo Ti Lè Rí Ìtùnú? No. 5

 • Ìjà Dáfídì àti Gòláyátì—Ṣé Ó Ṣẹlẹ̀? No. 5

 • Ìran Tó Sọ Àwọn Tó Ń Gbé Ní Ọ̀run, No. 6

 • Kí Ló Ń Ṣẹlẹ̀ Nígbà Tá A Bá Kú? No. 1

 • Kí Ni Ìjọba Ọlọ́run? No. 5

 • “Mo Múra Tán Láti Lọ” (Rèbékà), No. 3

 • Nígbà Tí Ẹnì Tó O Nífẹ̀ẹ́ Bá Kú, No. 3

 • Ǹjẹ́ Ayé Lè Bọ́ Lọ́wọ́ Ìwà Ipá? No. 4

 • Ohun Táwọn Aṣáájú Ẹ̀sìn Júù Sọ Pé Èèyàn Lè Torí Ẹ̀ Jáwèé Ìkọ̀sílẹ̀, No. 4

 • Ọ̀rọ̀ Àpọ́nlé Tó Ń Tuni Lára! (“ọmọbìnrin”), Nov.

 • Ṣé Àwọn Èèyàn Ló Dá Ẹ̀sìn Sílẹ̀? No. 4

 • Ṣé Gbogbo Àdúrà Ni Ọlọ́run Máa Ń Dáhùn? No. 6

 • Ṣé Lóòótọ́ Ni Pé Àwọn Kan Máa Ń Fún Èpò Sínú Oko Ẹlòmíì? Oct.

 • Ṣé Ó Ní Ipò Kan Tá A Gbọ́dọ̀ Wà Ká Tó Lè Gbàdúrà? No. 6

 • Ṣé Ó Pọndandan Kéèyàn Wà Nínú Ìsìn Kan? No. 4

 • Tá ni Èṣù? No. 2

 • “Ti Jèhófà Ni Ìjà Ogun Náà” (Dáfídì), No. 5