Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

ILÉ ÌṢỌ́ (Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́) April 2018

Àwọn àpilẹ̀kọ tá a máa kẹ́kọ̀ọ́ láti June 4 sí July 8, 2018 ló wà nínú Ilé Ìṣọ́ yìí.

Bá A Ṣe Lè Ní Òmìnira Tòótọ́

Ọ̀pọ̀ ló ń wá bí wọ́n á ṣe fòpin sí ipò òṣì, kẹ́lẹ́yàmẹ̀yà àti ìnilára. Àwọn mí ì máa ń fẹ́ ní òmìnira ọ̀rọ̀ sísọ àti òmìnira láti yan ohun tó wù wọ́n. Ǹjẹ́ ó ṣeé ṣe káwa èèyàn wà lómìnira lóòótọ́?

Jọ́sìn Jèhófà, Ọlọ́run Tí Ń Fúnni Ní Òmìnira

Ọ̀nà wo ni ẹ̀mí Ọlọ́run ti gbà dá wa sílẹ̀ lómìnira? Kí ló yẹ ká ṣe tá ò bá fẹ́ ṣi òmìnira tí Ọlọ́run fún wa lò?

Ẹ̀yin Arákùnrin Tá A Yàn Sípò​—Ẹ Kẹ́kọ̀ọ́ Lára Tímótì

Ó jọ pé ẹ̀rù ba Tímótì nígbà tó bẹ̀rẹ̀ sí í bá àpọ́sítélì Pọ́ọ̀lù ṣiṣẹ́, ó sì rò pé òun ò tóótun. Kí làwọn alàgbà àtàwọn ìránṣẹ́ iṣẹ́ òjíṣẹ́ lè kọ́ lára Tímótì?

Máa Fúnni Níṣìírí Bíi Ti Jèhófà

Kò sígbà tí àwa èèyàn Jèhófà kì í nílò ìṣírí.

Ìsinsìnyí Ló Yẹ Ká Máa Fún Ara Wa Níṣìírí Ju ti Ìgbàkigbà Rí Lọ

Bí ọjọ́ Jèhófà ṣe túbọ̀ ń sún mọ́lé, ó yẹ kọ́rọ̀ àwọn ará wa máa jẹ wá lọ́kàn, ká lè fún wọn níṣìírí nígbàkigbà tó bá yẹ.

Ẹ̀yin Ọ̀dọ́, Ṣé Ìjọsìn Jèhófà Ló Gbawájú ní Ìgbésí Ayé Yín?

Àwọn ọ̀dọ́ lè má mọ ohun tí wọ́n máa ṣe torí onírúurú nǹkan tó wà níwájú wọn. Báwo ni wọ́n ṣe lè ṣe ìpinnu tó mọ́gbọ́n dání nípa ọjọ́ ọ̀la wọn?

Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé

Kí nìdí tá ò fi fẹ́ káwọn èèyàn máa gbé àwọn ìtẹ̀jáde wa sórí ìkànnì mí ì tàbí sórí ìkànnì àjọlò?

Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé

Kí nìdí tá a fi ṣàtúnṣe sí Sáàmù 144 nínú Bíbélì Ìtumọ̀ Ayé Tuntun?