Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

JÍ! November 2015 | Èrò Tó Yẹ Ká Ní Nípa Owó

Èrò tí kò tọ́ nípa owó lè mú ká máa ṣìwà hù.

KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ

Èrò Tó Yẹ Ká Ní Nípa Owó

Àwọn ìbéèrè méje wà tó o lè fi yẹ ara rẹ wò bóyá èrò tó yẹ ló ní nípa owó.

TA LÓ ṢIṢẸ́ ÀRÀ YÌÍ?

Bí Awọ Aláǹgbá Thorny Devil Ṣe Ń Fa Omi Mu

Báwo ni aláǹgbá yìí ṣe ń fa omi láti ẹsẹ̀ rẹ̀ wá sí ẹnu rẹ̀?

ÌRÀNLỌ́WỌ́ FÚN ÌDÍLÉ

Bó O Ṣe Lè Tọrọ Àforíjì

Tó bá jẹ́ èmi kọ́ ni mo jẹ̀bi ńkọ́?

OJÚ ÌWÒYE BÍBÉLÌ

Ipò ÒṢÌ

Ṣé àwọn òtòṣì lè láyọ̀?

ÌRÀNLỌ́WỌ́ FÚN ÌDÍLÉ

Ìgbà Tó Yẹ Kó O Pa Dà Sọ́dọ̀ Àwọn Òbí Rẹ

Ṣé nǹkan ṣòro fún ẹ nígbà tó filé lẹ̀ láti lọ máa dá gbé? Àwọn ìmọ̀ràn yìí lè ràn ẹ́ lọ́wọ́.

Ohun Tó O Lè Ṣe Tí Èèyàn Rẹ Bá Ń Ṣàìsàn

Ìdààmú máa ń bá ẹnì tó bá lọ rí dókítà tàbí tí wọ́n dá dúró sí ilé ìwòsàn. Báwo lo ṣe lè ran èèyàn rẹ tó wà nírú ipò yìí lọ́wọ́?

OHUN TÓ Ń LỌ LÁYÉ

Nípa Ìdílé

Àwọn ìṣòro wo làwọn ìdílé sábà máa ń kojú? Ibo ni wọ́n ti lè rí ìmọ̀ràn tó máa ràn wọ́n lọ́wọ́?

Àwọn Nǹkan Míì Tó Wà Lórí Ìkànnì

Àwọn Ìbéèrè Táwọn Èèyàn Máa Ń Béèrè Nípa Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Wàá rí ìdáhùn tó ṣe pàtó sí àwọn ìbéèrè táwọn èèyàn sábà máa ń béèrè.

Eré Ọwọ́ fún Àwọn Ọmọdé

Lo àwọn eré ọwọ́ tó gbádùn mọ́ni tó dá Bíbélì yìí láti fi kọ́ àwọn ọmọ rẹ lẹ́kọ̀ọ́ nípa ìwà rere.