Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

JÍ! September 2015 | Ǹjẹ́ O Lè Pinnu Bí Ìgbésí Ayé Rẹ Ṣe Máa Rí?

Ṣé nǹkan kò lọ dáadáa fún bó o ṣe fẹ́ nígbèésí ayé rẹ? Wo ohun tó o lè ṣe sí àwọn ohun tó ń bá ẹ fínra.

KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ

Ǹjẹ́ O Lè Pinnu Bí Ìgbésí Ayé Rẹ Ṣe Máa Rí?

Kò yẹ kó o jẹ́ kí àwọn ìṣòro àìròtẹ́lẹ̀ paná ayọ̀ rẹ nígbèésí ayé.

KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ

Ohun Tó Jẹ́ Ìṣòro: Ìṣòro Tó Kọjá Agbára Wa

Ohun mẹ́rin tó o lè ṣe tó o bá kojú ìṣòro tó kọjá agbára rẹ.

KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ

Ohun Tó Jẹ́ Ìṣòro: Ojúṣe Tó Ń Wọni Lọ́rùn

Tó o bá fẹ́ máa ṣe gbogbo nǹkan, wàá dá ara rẹ lágara. Kí lo lè ṣe tí àwọn ojúṣe rẹ kò fi ní wọ̀ ẹ́ lọ́rùn?

KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ

Ohun Tó Jẹ́ Ìṣòro: Èrò Òdì

Ṣé ó máa ń ṣòro fún ẹ láti gbé àníyàn, ìbínú àti ìbànújẹ́ kúrò lọ́kàn? Wo àwọn nǹkan tó o lè ṣe sí i.

KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ

Ṣé O Lè Pinnu Bí Ìgbésí Ayé Rẹ Ṣe Máa Rí?

Ohun tó máa mú kó o lè pinnu bó o ṣe fẹ́ kí ìgbésí ayé rẹ rí kò le rárá.

ÌRÀNLỌ́WỌ́ FÚN ÌDÍLÉ

Bí Ìwọ àti Àfẹ́sọ́nà Rẹ Bá Fi Ara Yín Sílẹ̀

Bó o ṣe lè gbé e kúrò lọ́kàn bí àfẹ́sọ́nà rẹ bá sọ pé òun ò ṣe mọ́?

OJÚ ÌWÒYE BÍBÉLÌ

Iṣẹ́

Irú iṣẹ́ wo ló yẹ ká ṣe?

Ohun Tó Yẹ Kó O Mọ̀ Nípa Àìsàn Ibà

O lè dáàbò bo ara rẹ tó o bá ń gbé níbi tí ẹ̀fọn pọ̀ sí, tàbí tó o bá fẹ́ lọ sí ìlú tí ẹ̀fọn pọ̀ sí.

OJÚ ÌWÒYE BÍBÉLÌ

Àmúmọ́ra

Ǹjẹ́ Bíbélì sọ pé àwọn nǹkan kan wà tí a ò lè gbà mọ́ra?

TA LÓ ṢIṢẸ́ ÀRÀ YÌÍ?

Párì Ọ̀nì

Agbára tó fi ń deyín mọ́ nǹkan fi ìlọ́po mẹ́ta ju ti kìnnìún àti ẹkùn lọ, síbẹ̀ ó máa ń yára mọ nǹkan lára ju àwa èèyàn lọ. Kí nìdí?

Àwọn Nǹkan Míì Tó Wà Lórí Ìkànnì

Ohun Táwọn Ọ̀dọ́ Sọ Nípa Owó

Kẹ́kọ̀ọ́ nípa bó o ṣe lè fowó pa mọ́, bó ṣe yẹ kó o ná an àti bó ò ṣe ní sọ ara rẹ di ẹrú owó.

Jẹ́ Onínúure àti Ọ̀làwọ́

Wo bí Kọ́lá àti Tósìn ṣe túbọ̀ gbádùn ara wọn nígbà tí wọ́n jọ lo nǹkan ìṣeré wọn.