Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

JÍ! March 2015 | Nje Bibeli Wulo fun Wa Lonii?

Wo merin lara awon ilana inu re to fi han pe o si wulo lonii gege bo se wulo nigba ti won ko o.

KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ

Nje Bibeli Wulo Fun Wa Lonii?

Nigba ti Hilton fi ile sile, awon obi re ro pe ko le yiwa pa da mo. Nigba to pa da de leyin odun 12, won si i mo tori o ti yi pa da. Ki lo sele?

KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ

Jije Oloooto

Raquel i ba lowo repete ka ni o gba riba, sugbon o gba pe ere toun ri ju owo lo.

KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ

Ikora-Eni-Nijaanu

Ki lo ran okunrin kan to n je Cassius lowo lati maa ko ara e nijaanu?

KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ

Isotito Laaarin Tokotaya

Obinrin kan ri ibanuje ti aisooto maa n fa. Se aarin oun ati oko re tun le gun?

KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ

Ife

Ife ti Bibeli saba maa n menu kan ki i se ife aarin lokotaya.

ÌRÀNLỌ́WỌ́ FÚN ÌDÍLÉ

Bi O Se Le Sakoso Ibinu Re

Ilana Bibeli marun-un to le ran e lowo lati sakoso ibinu re.

Ogbon To N Daabo Boni

Ki ni itumo owe Bibeli to so pe: “Irapada okan eniyan ni oro re, sugbon eni ti o je alainilowo ko gbo ibawi mimuna”?

ÌRÀNLỌ́WỌ́ FÚN ÌDÍLÉ

Bi O Se Le Salaye Ohun Ti Iku Je fun Omo Re

Ohun merin to o le se lati dahun ibeere won, ta a si mu ki won fara da a ti eni ti won feran ba ku.

OJÚ ÌWÒYE BÍBÉLÌ

Iya

Se Olorun ri gbogbo iya ta a n je?

OJÚ ÌWÒYE BÍBÉLÌ

Mesaya

Nje o mo pe Bibeli so pe Mesaya naa maa ku ko to pari ise re?

Àwọn Nǹkan Míì Tó Wà Lórí Ìkànnì

Máa Wà ní Mímọ́ Tónítóní

Jèhófà ní ibi to máa ń tọ́jú àwọn nǹkan sí. Kọ́ bí o ṣe lè wà ní mímọ́ tónítóní!