Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

JÍ! January 2013 | Bó O Ṣe Lè Kọ́ Ọmọ Rẹ Níwà Ọmọlúwàbí Lóde Òní

Bó o ṣe lè bọ́ lọ́wọ́ àṣìṣe mẹta tí àwọn òbí máa ń ṣe.

Ohun Tó Ń Lọ Láyé

Kà nípa ohun tó ń lọ àtàwọn ohun tó o nífẹ̀ẹ́ sí yíká ayé.

ÌRÀNLỌ́WỌ́ FÚN ÌDÍLÉ

Bó O Ṣe Lè Máa Bá Ọmọ Rẹ Tó Ti Ń Bàlágà Sọ̀rọ̀

Ṣé kì í ṣòro fún ẹ láti bá ọmọ rẹ tó ṣẹ̀ ń bàlágà sọ̀rọ̀? Kí ló fa ìṣòro yìí?

ÌFỌ̀RỌ̀WÁNILẸ́NUWÒ

Onímọ̀ Sáyẹ́ǹsì Kan Ṣàlàyé Ohun Tó Gbà Gbọ́

Kà nípa àwọn ìsọfúnni tó dá lórí ìmọ̀ sáyẹ́ǹsì tó ran onímọ̀ sáyẹ́ǹsì yìí lọ́wọ́ láti gba Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run gbọ́.

COVER SUBJECT

Bó O Ṣe Lè Kọ́ Ọmọ Rẹ Níwà Ọmọlúwàbí Lóde Òní

Jẹ́ ká wo àwọn nǹkan mẹ́ta tó o lè ṣe tí ìwà ìbàjẹ́ tó ti gbòde kan yìí kò fi ní kó èèràn ràn àwọn ọmọ rẹ.

LANDS AND PEOPLES

Bá Wa Ká Lọ sí Ilẹ̀ Kamẹrúùnù

Kà nípa àwọn èèyàn orílẹ̀-èdè tó wà nílẹ̀ Áfíríkà yìí.

OJÚ ÌWÒYE BÍBÉLÌ

Párádísè

Ṣé ọ̀run ni Párádísè wà, àbí ilẹ̀ ayé ló máa wà? Àwọn wo ló máa gbé nínú Párádísè?

TA LÓ ṢIṢẸ́ ÀRÀ YÌÍ?

Bí ẹyẹ Godwit ṣe ń rìnrìn-àjò

Kà nípa bí ẹyẹ Godwit ṣe máa ń rin ìrìn-àjò ọjọ́ mẹ́jọ lọ́nà tó yani lẹ́nu gan-an.

Àwọn Nǹkan Míì Tó Wà Lórí Ìkànnì

Kí Ni Mo Lè Ṣe Tí Wọ́n Bá Ń Fi Ìṣekúṣe Lọ̀ Mí?

Kà nípa bí wọ́n ṣe máa ń fi ìṣekúṣe lọni àti ohun tó o lè ṣe tí wọ́n bá ń fi ìṣekúṣe lọ̀ ẹ́.