Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Ọwọ́ Ni Mo Fi Ń Ṣe Gbogbo Nǹkan

Ọwọ́ Ni Mo Fi Ń Ṣe Gbogbo Nǹkan

Wọ́n bí James Ryan tó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ní afọ́jú, nígbà tó yá, ó di adití. Wo fídíò yìí kó o lè mọ ìdí tó fi sọ pé òun ti jèrè ohun tó pọ̀ ju ohun tí òun pàdánù lọ bí ìdílé rẹ̀ àti ìjọ * tó wà ṣe ń ràn án lọ́wọ́.

^ ìpínrọ̀ 2 James nìkan ni Ẹlẹ́rìí Jèhófà nínú ìdílé rẹ̀.