Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

BÍBÉLÌ MÁA Ń YÍ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀWỌN ÈÈYÀN PA DÀ

Ọ̀rọ̀ Ẹ̀sìn Yọ Lọ́kàn Mi

Ọ̀rọ̀ Ẹ̀sìn Yọ Lọ́kàn Mi

Ó wu Tom pé kó nígbàgbọ́ nínú Ọlọ́run, ṣùgbọ́n ó bà á nínú jẹ́ láti rí i pé irọ́ làwọn onísìn fi ń kọ́ni. Wo bí ohun tó kọ́ nínú Bíbélì ṣe jẹ́ kó ní ìrètí.