Ẹsẹ Bíbélì kan tí Hércules kà ló mú kó dá a lójú pé ò lè yí ìwà ìbínú fùfù rẹ̀ pa dà, kó sì di ẹni pẹ̀lẹ́.