Wo fídíò yìí, kó o rí bí ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì ṣe yí ìgbésí ayé ẹlẹ́wọ̀n kan pa dà.​—Sáàmù 68:6.