Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Oríléeṣẹ́ Tuntun—Ohun Mánigbàgbé Nínú Ìtàn Wa

Oríléeṣẹ́ Tuntun—Ohun Mánigbàgbé Nínú Ìtàn Wa

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà ń kọ́ oríléeṣẹ́ wa tuntun lọ́wọ́ nílùú Warwick, ní New York. Iṣẹ́ ńlá ni iṣẹ́ yìí, káàkiri orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà lọ̀pọ̀ èèyàn sì ti yọ̀ǹda ara wọn láti wá kọ́wọ́ ti iṣẹ́ yìí. Tinútinú ni wọ́n ṣe é, wọ́n sì ń ṣiṣẹ́ kára láìgba owó torí wọ́n gbà pé Ọlọ́run làwọn ń ṣe é fún. Wo ohun ribiribi táwọn òṣìṣẹ́ yìí gbé ṣe!