Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Àwọn Iṣẹ́ Ìkọ́lé

ÀWỌN IṢẸ́ ÌKỌ́LÉ

Fọ́tò Oríléeṣẹ́ Wa Tuntun ní Warwick, Apá 7 (September 2016 sí February 2017)

Gbogbo ilé tó wà ní oríléeṣẹ́ wa ní Warwick la ti ń lò báyìí. Ní Àwọn Ọ́fíìsì àti Ilé Tó Wà fún Onírúurú Iṣẹ́, ó lé ní 250 èèyàn tó ṣiṣẹ́ lórí àwọn ìpàtẹ yìí látìbẹ̀rẹ̀ dé ìparí àtàwọn ohun ìṣẹ̀ǹbáyé tó wà nínú rẹ̀.

ÀWỌN IṢẸ́ ÌKỌ́LÉ

Fọ́tò Oríléeṣẹ́ Wa Tuntun ní Warwick, Apá 7 (September 2016 sí February 2017)

Gbogbo ilé tó wà ní oríléeṣẹ́ wa ní Warwick la ti ń lò báyìí. Ní Àwọn Ọ́fíìsì àti Ilé Tó Wà fún Onírúurú Iṣẹ́, ó lé ní 250 èèyàn tó ṣiṣẹ́ lórí àwọn ìpàtẹ yìí látìbẹ̀rẹ̀ dé ìparí àtàwọn ohun ìṣẹ̀ǹbáyé tó wà nínú rẹ̀.

Àwọn Fọ́tò Iṣẹ́ Ìkọ́lé Ẹ̀ka Ọ́fíìsì Wa ní Ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì, Apá 2 (September 2015 sí August 2016)

Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà tó yọ̀ǹda ara wọn àtàwọn agbaṣẹ́ṣe ti ń ṣètò ilẹ̀ tí wọ́n máa kọ́ ẹ̀ka ọ́fíìsì náà sí àti ibi tí wọ́n máa kọ́lé tí wọ́n á máa kó irinṣẹ́ sí, táwọn òṣìṣẹ́ á sì máa gbé kí wọ́n tó ṣiṣẹ́ ìkọ́lé ńlá yìí tán.

Oríléeṣẹ́ Tuntun—Ohun Mánigbàgbé Nínú Ìtàn Wa

Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ń kọ́ oríléeṣẹ́ wọn tuntun lọ́wọ́ nílùú Warwick, ní New York. Ó dá wọn lójú pé Ọlọ́run wà lẹ́yìn wọn lẹ́nu iṣẹ́ pàtàkì tí wọ́n ń ṣe yìí.

Wọn Ò Pa Ẹran Igbó Lára Nílùú Chelmsford

Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà tó wà ní Ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì ti bẹ̀rẹ̀ sí í kọ́ ẹ̀ka ọ́fíìsì wọn tuntun sí tòsí ìlú Chelmsford. Kí ni wọ́n ń ṣe kí wọ́n má bàa pa ẹran igbó lára?

Fọ́tò Oríléeṣẹ́ Wa Tuntun ní Warwick, Apá 6 (March sí August 2016)

Àwọn oṣù tí wọ́n lò gbẹ̀yìn níbi iṣẹ́ ìkọ́lé tó ń lọ ní oríléeṣẹ́ àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà nílùú Warwick, ní New York.

Ohun Táwọn Onílé Sọ

Báwo ló ṣe rí lára àwọn onílé kan pé àwọn yá àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ní ilé?

Àwọn Ẹlẹ́rìí Ò Pa Àwọn Ẹran Igbó àti Àyíká Lára Nílùú Warwick

Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ti bẹ̀rẹ̀ sí í kọ́ oríléeṣẹ́ wọn tuntun sí ìpínlẹ̀ New York. Kí ni wọ́n ń ṣe kí wọn má bàa pa àyíká lára?

Fọ́tò Oríléeṣẹ́ Wa Tuntun ní Warwick, Apá 5 (September 2015 sí February 2016)

Wọ́n ṣe iná sí Àwọn Ọ́fíìsì àti Ilé Tó Wà fún Onírúurú Iṣẹ́, wọ́n ṣe òrùlé tó máa ń jẹ́ kí ìmọ́lẹ̀ wọlé síbẹ̀, wọ́n tún to òkúta pẹlẹbẹ-pẹlẹbẹ sílẹ̀, wọ́n sì ṣe ìbòrí sí ojú ọ̀nà táwọn èèyàn á máa gbà.

Bọ́rọ̀ Ṣe Rí Lára Àwọn Tó Ń Bá Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Ṣiṣẹ́ ní Warwick

Ìrírí wo làwọn òṣìṣẹ́ kan tí kì í ṣe Ẹlẹ́rìí àtàwọn tó ń wa bọ́ọ̀sì ní nígbà tí wọ́n ń bá àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà ṣiṣẹ́ ìkọ́lé?

Àwọn Fọ́tò Iṣẹ́ Ìkọ́lé Ẹ̀ka Ọ́fíìsì Wa ní Ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì, Apá 1 (January sí August 2015)

Wo bí iṣẹ́ ṣe ń lọ sí níbi tá a ti ń kọ́ ẹ̀ka ọ́fíìsì wa tuntun ti ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì ní tòsí ìlú Chelmsford ní Essex.

Fọ́tò Oríléeṣẹ́ Wa Tuntun ní Warwick, Apá 4 (May sí August 2015)

Wọ́n parí iṣẹ́ lórí ògiri àti òrùlé ilé gbígbé kan àti àwọn afárá tó so àwọn ilé pọ̀, wọ́n sì ti bẹ̀rẹ̀ sí í tún ojú ilẹ̀ ṣe.

Àwọn Fọ́tò Iṣẹ́ Ìkọ́lé Ẹ̀ka Ọ́fíìsì Wa ní Philippines, Apá 1 (February 2014 sí May 2015)

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà ń kọ́ àwọn ilé tuntun sí ẹ̀ka ọ́fíìsì wa tó wà nílùú Quezon ní Philippines, a sì ń tún àwọn èyí tó ti wà níbẹ̀ tẹ́lẹ̀ ṣe.

Fọ́tò Orílé-Iṣẹ́ Wa Tuntun ní Warwick—Apá 3 (January sí April 2015)

Ní February, àwọn ẹgbẹ̀rún méjì ààbọ̀ [2,500] òṣìṣẹ́ ló wá ṣiṣẹ́ ní Warwick lójoojúmọ́, àwọn òṣìṣẹ́ ọgọ́rùn-ún márùn ún [500] ló wá ń ṣiṣẹ́ lọ́sọ̀ọ̀sẹ̀. Wo bí iṣẹ́ náà ṣe ń tẹ̀ síwájú.

Ìlú Warwick Gbàlejò

Àwọn aráàlú Warwick ní ìpínlẹ̀ New York sọ̀rọ̀ nípa bó ṣe rí lára wọn láti bá àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà ṣiṣẹ́ ní oríléeṣẹ́ wa tuntun tá à ń kọ́.

Àwọn Gbọ̀ngàn Ìjọba Tá A Kọ́ fún Mílíọ̀nù Kan Àwọn Ẹlẹ́rìí

Látọdún 1999, Gbọ̀ngàn Ìjọba tó lé ní 5,000 la ti kọ́ ní Mẹ́síkò àtàwọn orílẹ̀-èdè méje tó wà ní ilẹ̀ Central America. Kí ló ń mú kó wu àwọn tí kì í ṣe Ẹlẹ́rìí Jèhófà pé kí wọ́n rí Gbọ̀ngàn Ìjọba tuntun ládùúgbò wọn?

Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Máa Kọ́ Orílé-Iṣẹ́ Tuntun

Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ti wà ní Brooklyn, nílùú New York láti ọdún 1909. Kí ló dé tí wọ́n fi fẹ́ kó lọ sí àríwá ìlú New York?