Ní August 28, 2012, àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà ṣe àtúntò ìkànnì jw.org, a sì bẹ̀rẹ̀ sí i lò ó. Wo bí àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà àti àwọn tí kìí ṣe Ẹlẹ́rìí ṣe jàǹfààní ìkànnì yìí.