Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

Bí Nǹkan Ṣe Rí Ní Bẹ́tẹ́lì

BÍ NǸKAN ṢE RÍ NÍ BẸ́TẸ́LÌ

Bí Wọ́n Ṣe Mọ Iná Pa

Ohun tó ṣẹlẹ̀ lọ́jọ́ kan tí iná ṣẹ́ yọ ò jẹ́ kí gbogbo ìdálẹ́kọ̀ọ́ tí wọ́n ti gbà ṣòfò.

BÍ NǸKAN ṢE RÍ NÍ BẸ́TẸ́LÌ

Bí Wọ́n Ṣe Mọ Iná Pa

Ohun tó ṣẹlẹ̀ lọ́jọ́ kan tí iná ṣẹ́ yọ ò jẹ́ kí gbogbo ìdálẹ́kọ̀ọ́ tí wọ́n ti gbà ṣòfò.

A Pè Ẹ́ Kó O Wá Wo Àwọn Ọ́fíìsì Wa Tó Wà ní Bẹ́tẹ́lì Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà

Wàá rí Oríléeṣẹ́ Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà àti ẹ̀ka ọ́fíìsì wa lórílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà.

Kí Là Ń Ṣe ní Àwọn Ẹ̀ka Ọ́fí ìsì Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà?

A máa ń mú àwọn àlejò káàkiri ẹ̀ka ọ́fí ìsì wa, kí wọ́n lè rí ohun tí à ń ṣe níbẹ̀. A pè ọ́ pé kí o wá!

Ọ̀pọ̀ Èèyàn Wá Wo Ẹ̀ka Ọ́fíìsì Wa ní Central America

Ó gba ìsapá káwọn kan tó lè wá wo ẹ̀ka ọ́fíìsì wa. Ọ̀pọ̀ èèyàn lọ́ yá bọ́ọ̀sì akérò, wọ́n sì fi ọ̀pọ̀ ọjọ́ rìnrìn àjò wá síbẹ̀. Kí làwọn ọ̀dọ́ àtàwọn ọmọdé sọ nígbà tí wọ́n wá wo Bẹ́tẹ́lì?

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Pa Àwọn Ẹ̀ka Ọ́fíìsì Wa Kan Pọ̀

Kà nípa ìdí pàtàkì méjì tá a fi pa àwọn ẹ̀ka ọ́fíìsì tó lé ní mẹ́ẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n [25] pọ̀.

Àkànṣe Ìpàtẹ Bíbélì

Láti ìgbà tí Jèhófà Ọlọ́run ti dá èèyàn sáyé ló ti jẹ́ kí wọ́n mọ orúkọ òun. Wo fídíò yìí kó o lè rí bí àwọn ìtúmọ̀ Bíbélì kan ṣe pa orúkọ Ọlọ́run mọ́ láti ọ̀pọ̀ ọdún títí di ìsìnsìnyí.

Ìpàtẹ Bíbélì Tó Ń Fògo fún Orúkọ Jèhófà

A ṣí ibi ìpàtẹ Bíbélì kan sí oríléeṣẹ́ wa ní ọdún 2013. Ọ̀pọ̀ Bíbélì tó ṣọ̀wọ́n tó sì ṣeyebíye la ti rí gbà.