Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

A Fi Iṣẹ́ Títúmọ̀ “Àwọn Ọ̀rọ̀ Ìkéde Ọlọ́wọ̀ Ti Ọlọ́run” Síkàáwọ́ Wọn—Róòmù 3:2

A Fi Iṣẹ́ Títúmọ̀ “Àwọn Ọ̀rọ̀ Ìkéde Ọlọ́wọ̀ Ti Ọlọ́run” Síkàáwọ́ Wọn—Róòmù 3:2

A lè rí òtítọ́ Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìtúmọ̀ Bíbélì. Láti ọ̀pọ̀ ọdún títí di báyìí, àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ti fi ọ̀pọ̀ Bíbélì kọ́ àwọn èèyàn lẹ́kọ̀ọ́ òtítọ́. Kí nìdí tí àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà fi dáwọ́ lé iṣẹ́ ìtumọ̀ Bíbélì tiwọn sí èdè Gẹ̀ẹ́sì òde òní? Àǹfààní wo ni ohun tí wọ́n dáwọ́ lé yìí ti mú wá? Wo fídíò tá a pe àkọ́lé rẹ̀ ní A Fi Iṣẹ́ Títúmọ̀ “Àwọn Ọ̀rọ̀ Ìkéde Ọlọ́wọ̀ Ti Ọlọ́run” Síkàáwọ́ Wọn​—Róòmù 3:2.