Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

Iṣẹ́ Ìtẹ̀wé Wa

IṢẸ́ ÌTẸ̀WÉ

A Túmọ̀ Ìtẹ̀jáde Sí Èdè Àwọn Adití Lọ́nà ti Quebec

Kí nìdí tó fi ṣe pàtàkì kí wọ́n túmọ̀ àwọn ìtẹ̀jáde sí èdè àwọn adití?

IṢẸ́ ÌTẸ̀WÉ

A Túmọ̀ Ìtẹ̀jáde Sí Èdè Àwọn Adití Lọ́nà ti Quebec

Kí nìdí tó fi ṣe pàtàkì kí wọ́n túmọ̀ àwọn ìtẹ̀jáde sí èdè àwọn adití?

A Nífẹ̀ẹ́ Òtítọ́, A sì Ní Ọ̀wọ́ Tó Jinlẹ̀ fún Òtítọ́

Ẹnikẹ́ni tó bá ka àwọn ìwé wa tàbí tó wo àwọn fídíò tó wà lórí ìkànnì wa lè fọkàn balẹ̀ torí a fara balẹ̀ ṣe ìwádìí lórí wọn, wọ́n sì jẹ́ òótọ́.

Bá A Ṣe Ń Ya Àwọn Àwòrán Tó Gbé Kókó Ọ̀rọ̀ Jáde

Báwo ni àwọn ayàwòrán wa ṣe ń ya àwọn àwòrán tó fani mọ́ra, tó sì bá kókó ọ̀rọ̀ inú àwọn ìtẹ̀jáde wa mu?

Àwọn Èèyàn Orílẹ̀-Èdè Estonia Mọyì “Iṣẹ́ Ńlá” Tá A Ṣe

Bíbélì Ìtúmọ̀ Ayé Tuntun wà lára àwọn ìwé tó fakọ yọ jù lọ tí wọ́n mú, tí wọ́n sì fún ní Àmì Ẹ̀yẹ Ìwé Tó Dára Jù Lọ ní Orílẹ̀-Èdè Estonia lọ́dún 2014.

Wọ́n Pín Ìwé Tó Ṣàlàyé Bíbélì Lórílẹ̀-Èdè Congo

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà yọ̀ǹda ara wa lóṣooṣù láti kó Bíbélì àtàwọn ìwé tó ṣàlàyé Bíbélì lọ fún àwọn èèyàn ní Orílẹ̀-èdè Congo.

Bíbélì Àtẹ́tísí Tó Wà fún Gbogbo Èèyàn

Onírúurú ohùn la gbà sílẹ̀ nínú àtẹ́tísí Bíbélì Ìtumọ̀ Ayé Tuntun tí a tún ṣe lọ́dún 2013 ní èdè Gẹ̀ẹ́sì.

Orin Ìyìn sí Ọlọ́run Lónírúurú Èdè

Kà nípa àwọn ìṣòro tó wà nínú títú orin sí onírúurú èdè.

Ojú Ìwé Rẹ̀ Ò Pọ̀, Ó sì Wà ní Ọ̀pọ̀ Èdè

Bẹ̀rẹ̀ láti January 2013, a máa dín ojú ìwé àwọn ìwé ìròyìn Ilé Ìṣọ́ àti Jí! kù. Kí nìdí?

Fídíò Kékeré: “Ọpẹ́lọpẹ́ Rẹ̀ Lára Mi”

Wo fídíò yìí tó dá lórí ọkùnrin afọ́jú kan tó jàǹfààní nínú Bíbélì tí wọ́n ṣe fún àwọn afọ́jú.

A Fi Iṣẹ́ Títúmọ̀ “Àwọn Ọ̀rọ̀ Ìkéde Ọlọ́wọ̀ Ti Ọlọ́run” Síkàáwọ́ Wọn—Róòmù 3:2

Láti ọ̀pọ̀ ọdún títí di báyìí, àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ti fi ọ̀pọ̀ Bíbélì kọ́ àwọn èèyàn lẹ́kọ̀ọ́ òtítọ́. Kí nìdí tí wọ́n fi ṣe ìtúmọ̀ Bíbélì sí èdè Gẹ̀ẹ́sì òde òní?

Wọ́n Wá Kọrin

Ogójì ọdún sẹ́yìn làwọn arákùnrin àtàwọn arábìnrin ti ń wá láti ibi ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ lágbàáyé kí wọ́n lè kọ orin tá ó máa lò fún ìjọsìn wa àtàwọn fídíò tá à ń ṣe jáde.