Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Ó Ń Ṣe Wá Bíi Kípàdé Náà Má Parí

Ó Ń Ṣe Wá Bíi Kípàdé Náà Má Parí

Wo fídíò yìí, ó dá lórí àkànṣe Àpéjọ Àgbègbè tó wáyé nílùú Yangon, lórílẹ̀-èdè Myanmar. Ẹ̀rí ńlá làkànṣe Àpéjọ Àgbègbè yẹn jẹ́, pé ojúlówó ẹgbẹ́ ará ni wá, a sì wà níṣọ̀kan lórílẹ̀-èdè táwọn ará ò ti fi bẹ́ẹ̀ láǹfààní láti rí àwọn ará wa látàwọn orílẹ̀-èdè míì fọ́pọ̀ ọdún.

 

Mọ Púpọ̀ Sí I

OHUN TÍ BÍBÉLÌ SỌ

Kí Ni Ìjọba Ọlọ́run Máa Ṣe?

Kọ́ nípa ohun tó máa wáyé nígbà tí Ìjọba Ọlọ́run bá ń ṣàkóso gbogbo aye.

ÀWỌN WO LÓ Ń ṢE ÌFẸ́ JÈHÓFÀ LÓDE ÒNÍ?

Kí Nìdí Tí Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Fi Ń Lọ Sí Àwọn Àpéjọ Ńlá?

Lọ́dọọdún, a máa ń péjọ lẹ́ẹ̀mẹta lákànṣe fún ìpàdé. Báwo lo ṣe lè jàǹfààní nígbà tó o bá lọ sí irú àpéjọ bẹ́ẹ̀?