Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

Ìsọfúnni Nípa Ọ́fíìsì àti Rírìn Yí Ká Ọgbà

Tayọ̀tayọ̀ la pè ẹ́ kó o wá rìn yí ká ọ́fíìsì wa àtàwọn ibi tá a ti ń tẹ̀wé. Wá ọ́fíìsì wa tó o lè lọ àti àsìkò tó o lè rìn yí ọgbà wa ká.

Venezuela

Av. Intercomunal La Victoria-El Consejo

Frente a La Mora II

LA VICTORIA 2121 ESTADO ARAGUA

VENEZUELA

+58 244-400-5000

Wíwo Ọgbà Wa Yíká

Monday sí Friday

8:00 àárọ̀ sí 11:00 àárọ̀ àti 1:00 ọ̀sán sí 4:00 ìrọ̀lẹ́

Ó máa gba wákàtí 1

Àwọn iṣẹ́ tí à ń ṣe níbẹ̀

À ń túmọ̀ àwọn ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì sí Èdè Àwọn Adití Lọ́nà ti Venezuelan. À ń kó àwọn ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́ tí ìwọ̀n wọn tó tọ́ọ̀nù mẹ́tàdínlọ́gbọ̀n [27] ránṣẹ́ lóṣooṣù ní èdè mọ́kàndínlọ́gbọ̀n [29] síbi tí wọ́n ti nílò wọn. À ń bójú tó iṣẹ́ àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà tó lé ní ẹgbẹ̀rún márùnlélọ́gọ́fà [125,000] lórílẹ̀-èdè Venezuela.

Wa ìwé pẹlẹbẹ tó ń ṣàlàyé ẹ̀ka ọ́fíìsì wa jáde.