Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

Ìsọfúnni Nípa Ọ́fíìsì àti Rírìn Yí Ká Ọgbà

Tayọ̀tayọ̀ la pè ẹ́ kó o wá rìn yí ká ọ́fíìsì wa àtàwọn ibi tá a ti ń tẹ̀wé. Wá ọ́fíìsì wa tó o lè lọ àti àsìkò tó o lè rìn yí ọgbà wa ká.

South Africa

1 Robert Broom Drive East

Rangeview

KRUGERSDORP

1739

SOUTH AFRICA

+27 11-761-1000

Wíwo Ọgbà Wa Yíká

Monday sí Friday

8:00 àárọ̀ sí 11:00 àárọ̀ àti 1:00 ọ̀sán sí 4:00 ìrọ̀lẹ́

Ó máa gba wákàtí 2

Àwọn iṣẹ́ tí à ń ṣe níbẹ̀

À ń tẹ àwọn ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́, ìwé ìròyìn, ìwé pẹlẹbẹ àti ìwé àṣàrò kúkúrú ní èdè mọ́kànlélọ́gọ́fà [121], a sì ń kó wọn ránṣẹ́ sí ẹgbàafà ìjọ [12,000] lórílẹ̀-èdè mọ́kànlá. À ń tú ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì sí ogún [20] èdè. A tún ń ṣètìlẹ́yìn fún iṣẹ́ kíkọ́ Gbọ̀ngàn Ìjọba ní orílẹ̀-èdè méjìlélógójì [42].

Wa ìwé pẹlẹbẹ tó ń ṣàlàyé ẹ̀ka ọ́fíìsì wa jáde.