Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Ìsọfúnni Nípa Ọ́fíìsì àti Rírìn Yí Ká Ọgbà

Tayọ̀tayọ̀ la pè ẹ́ kó o wá rìn yí ká ọ́fíìsì wa àtàwọn ibi tá a ti ń tẹ̀wé. Wá ọ́fíìsì wa tó o lè lọ àti àsìkò tó o lè rìn yí ọgbà wa ká.

Slovakia

Pekna cesta 17

831 52 BRATISLAVA 34

SLOVAK REPUBLIC

+421 2-49107611

Wíwo Ọgbà Wa Yíká

Monday sí Friday

8:00 àárọ̀ sí 10:30 àárọ̀ àti 1:00 ọ̀sán sí 3:30 ọ̀sán

Ó máa gba ìṣẹ́jú 90

Àwọn iṣẹ́ tí à ń ṣe níbẹ̀

À ń bójú tó iṣẹ́ àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà tó ju ẹgbàá mẹ́tàlá ó lé ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀ta [26,500] ní orílẹ̀-èdè Czech Republic àti Slovakia. À ń túmọ̀ àwọn ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì sí èdè Slovak àti Èdè Àwọn Adití Lọ́nà ti Slovak. À ń kó ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì ránṣẹ́ sí àwọn ìjọ ní orílẹ̀-èdè Austria, Czech Republic, Slovakia àti Slovenia.

Wa ìwé pẹlẹbẹ tó ń ṣàlàyé ẹ̀ka ọ́fíìsì wa jáde.