Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

Ìsọfúnni Nípa Ọ́fíìsì àti Rírìn Yí Ká Ọgbà

Tayọ̀tayọ̀ la pè ẹ́ kó o wá rìn yí ká ọ́fíìsì wa àtàwọn ibi tá a ti ń tẹ̀wé. Wá ọ́fíìsì wa tó o lè lọ àti àsìkò tó o lè rìn yí ọgbà wa ká.

Poland

Świadkowie Jehowy w Polsce

ul. Warszawska 14

05-830 NADARZYN

POLAND

+48 22-739-16-00

Wíwo Ọgbà Wa Yíká

Monday sí Friday

8:00 àárọ̀ sí 10:00 àárọ̀ àti 1:00 ọ̀sán sí 3:0 ọ̀sán

Bóyá iye ẹ̀yin tẹ́ ẹ̀ ń bọ̀ pọ̀ tàbí ẹ kéré, ẹ jọ̀ọ́ ẹ pè kẹ́ ẹ tó wá wo ọgbà wa yíká

Ó máa gba wákàtí 2

Àwọn iṣẹ́ tí à ń ṣe níbẹ̀

À ń túmọ̀ àwọn ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì sí èdè Polish. A máa ń sọ ìtàn àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà ní orílẹ̀-èdè Poland fún àwọn tó wá wo ọgbà wa.

Wa ìwé pẹlẹbẹ tó ń ṣàlàyé ẹ̀ka ọ́fíìsì wa jáde.