Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Ìsọfúnni Nípa Ọ́fíìsì àti Rírìn Yí Ká Ọgbà

Tayọ̀tayọ̀ la pè ẹ́ kó o wá rìn yí ká ọ́fíìsì wa àtàwọn ibi tá a ti ń tẹ̀wé. Wá ọ́fíìsì wa tó o lè lọ àti àsìkò tó o lè rìn yí ọgbà wa ká.

Philippines

186 Roosevelt Ave

San Francisco del Monte

1105 QUEZON CITY

PHILIPPINES

+63 2-224-4444

Wíwo Ọgbà Wa Yíká

Monday sí Friday

8:00 àárọ̀ sí 11:00 àárọ̀ àti 1:00 ọ̀sán sí 4:00 ìrọ̀lẹ́

Ó máa gba wákàtí kan ààbọ̀

Àwọn iṣẹ́ tí à ń ṣe níbẹ̀

À ń tú ìwé ìròyìn Ilé Ìṣọ́ sí mẹ́jọ nínú àwọn èdè tí wọ́n ń lò jù nílẹ̀ Philippines. À ń gba ohun àtẹ́tísí àti ti fídíò sílẹ̀ ní èdè mẹ́wàá. À ń kó ìtẹ̀jáde ránṣẹ́ sí ìjọ 3,315.

Wa ìwé pẹlẹbẹ tó ń ṣàlàyé nípa ẹ̀ka ọ́fíìsì wa jáde.