Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Ìsọfúnni Nípa Ọ́fíìsì àti Rírìn Yí Ká Ọgbà

Tayọ̀tayọ̀ la pè ẹ́ kó o wá rìn yí ká ọ́fíìsì wa àtàwọn ibi tá a ti ń tẹ̀wé. Wá ọ́fíìsì wa tó o lè lọ àti àsìkò tó o lè rìn yí ọgbà wa ká.

Peru

Jirón El Cortijo 329

Monterrico Chico

LIMA 33

PERU

+51 1-​708-​9000

Wíwo Ọgbà Wa Yíká

Monday sí Friday

8:00 àárọ̀ sí 11:00 àárọ̀ àti 1:00 ọ̀sán sí 4:00 ìrọ̀lẹ́

Ó máa gba wákàtí 1

Àwọn iṣẹ́ tí à ń ṣe níbẹ̀

À ń túmọ̀ ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì sí èdè Ashaninka, Awajun, Quechua (Ancash), Quechua (Ayacucho), Quechua (Cuzco), Quechua (Huallaga Huánuco), Quechua (Huaylla Wanca), Èdè Àwọn Adití Lọ́nà ti Peruvian àti Shipibo-Conibo

Wa ìwé pẹlẹbẹ tó ń ṣàlàyé ẹ̀ka ọ́fíìsì wa jáde.