Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

Ìsọfúnni Nípa Ọ́fíìsì àti Rírìn Yí Ká Ọgbà

Tayọ̀tayọ̀ la pè ẹ́ kó o wá rìn yí ká ọ́fíìsì wa àtàwọn ibi tá a ti ń tẹ̀wé. Wá ọ́fíìsì wa tó o lè lọ àti àsìkò tó o lè rìn yí ọgbà wa ká.

Paraguay

Asociación Torre de Vigía de Biblias y Tratados

San Roque González 234

Ruta 1, Km. 17

B° 25 de Mayo

PY - 2560 CAPIATA

PARAGUAY

+595-​21-​237-​8390

Wíwo Ọgbà Wa Yíká

Monday sí Friday

8:00 àárọ̀, 9:00 àárọ̀, 10:00 àárọ̀, 1:45 ọ̀sán, 2:30 ọ̀sán àti 3:​30 ìrọ̀lẹ́

Ó máa gba wákàtí kan àti ìṣẹ́jú 15

Àwọn iṣẹ́ tí à ń ṣe níbẹ̀

À ń bójú tó ìṣẹ́ àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà ní Paraguay. À ń tú àwọn ìwé tó dá lórí Bíbélì sí èdè Guarani, Nivaclé àti Èdè Adití Lọ́nà ti Paraguay. A tún máa ń gba ohùn sílẹ̀, a sì máa ń ṣe fídíò fún àwọn ìtẹ̀jáde láwọn èdè yìí.

Wa ìwé pẹlẹbẹ tó ń ṣàlàyé nípa ẹ̀ka ọ́fíìsì wa jáde.