Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Ìsọfúnni Nípa Ọ́fíìsì àti Rírìn Yí Ká Ọgbà

Tayọ̀tayọ̀ la pè ẹ́ kó o wá rìn yí ká ọ́fíìsì wa àtàwọn ibi tá a ti ń tẹ̀wé. Wá ọ́fíìsì wa tó o lè lọ àti àsìkò tó o lè rìn yí ọgbà wa ká.

Netherlands

Christelijke Gemeente van Jehovah’s Getuigen in Nederland

Noordbargerstraat 77

7812 AA EMMEN

NETHERLANDS

+31 591-683555

Wíwo Ọgbà Wa Yíká

Monday sí Friday

8:00 àárọ̀ sí 10:30 àárọ̀ àti 1:00 ọ̀sán sí 3:00 ìrọ̀lẹ́

Ó máa gba wákàtí 1

Àwọn iṣẹ́ tí à ń ṣe níbẹ̀

À ń túmọ̀ àwọn ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì sí èdè Dutch. À ń ṣe ìwé àwọn afọ́jú ní èdè méjìlá ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀. A tún máa ń gba ohun sílẹ̀ a sì máa ń ṣe àwọn fídíò ní ọ̀pọ̀ èdè.

Wa ìwé pẹlẹbẹ tó ń ṣàlàyé ẹ̀ka ọ́fíìsì wa jáde.