Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

Ìsọfúnni Nípa Ọ́fíìsì àti Rírìn Yí Ká Ọgbà

Tayọ̀tayọ̀ la pè ẹ́ kó o wá rìn yí ká ọ́fíìsì wa àtàwọn ibi tá a ti ń tẹ̀wé. Wá ọ́fíìsì wa tó o lè lọ àti àsìkò tó o lè rìn yí ọgbà wa ká.

Myanmar

94-B Inya Rd

YANGON

MYANMAR

+95 1-2305692

+95 1-2305693

+95 1-512699

+95 1-511035

Wíwo Ọgbà Wa Yíká

Monday sí Friday

7:30 àárọ̀ sí 11:00 àárọ̀ àti 1:00 ọ̀sán sí 3:00 ọ̀sán

Ó máa gba wákàtí kan

Àwọn iṣẹ́ tí à ń ṣe níbẹ̀

À ń tú àwọn ìwé tó dá lórí Bíbélì sí èdè Myanmar, Chin (Hakha), Kachin, Karen (S’gaw), Mizo àtàwọn èdè mẹ́wàá míì.

Wa ìwé pẹlẹbẹ tó ń ṣàlàyé nípa ẹ̀ka ọ́fíìsì wa jáde.