Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Ìsọfúnni Nípa Ọ́fíìsì àti Rírìn Yí Ká Ọgbà

Tayọ̀tayọ̀ la pè ẹ́ kó o wá rìn yí ká ọ́fíìsì wa àtàwọn ibi tá a ti ń tẹ̀wé. Wá ọ́fíìsì wa tó o lè lọ àti àsìkò tó o lè rìn yí ọgbà wa ká.

Mozambique

Rua da Micaia No. 160

Bairro Triunfo

Costa do Sol

MAPUTO

MOZAMBIQUE

+258 21-450-500

Wíwo Ọgbà Wa Yíká

Monday sí Friday

8:00 àárọ̀ sí 11:00 àárọ̀ àti 1:00 ọ̀sán sí 3:30 ọ̀sán

Ó máa gba wákàtí kan

Àwọn iṣẹ́ tí à ń ṣe níbẹ̀

Ẹ̀ka ọ́fíìsì wa lórílẹ̀-èdè Mozambique ń bójú tó iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì táwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà tí iye wọn jẹ́ 59,990 ń ṣe. Wọ́n ń túmọ̀ àwọn ìwé tó dá lórí Bíbélì sí nǹkan bí ogún [20] èdè níbẹ̀, wọ́n sì ń kó o ránṣẹ́ sí ìjọ 1,254 jákèjádò orílẹ̀-èdè náà. A máa ń sọ ìtàn àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà lórílẹ̀-èdè Mozambique ní ṣókí fún àwọn tó bá wá wo ọgbà wa.

Wa ìwé pẹlẹbẹ tó ń ṣàlàyé nípa ẹ̀ka ọ́fíìsì wa jáde.