Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

Ìsọfúnni Nípa Ọ́fíìsì àti Rírìn Yí Ká Ọgbà

Tayọ̀tayọ̀ la pè ẹ́ kó o wá rìn yí ká ọ́fíìsì wa àtàwọn ibi tá a ti ń tẹ̀wé. Wá ọ́fíìsì wa tó o lè lọ àti àsìkò tó o lè rìn yí ọgbà wa ká.

Mexico

Ave Jardin No. 10

Fraccionamiento El Tejocote

56265 TEXCOCO, MEX

MEXICO

+52 555-133-3000

+52 555-858-0100

Wíwo Ọgbà Wa Yíká

Monday sí Friday

8:00 àárọ̀ sí 11:00 àárọ̀ àti 1:00 ọ̀sán sí 4:00 ìrọ̀lẹ́

Ó máa gba wákàtí méjì ààbọ̀

Àwọn iṣẹ́ tí à ń ṣe níbẹ̀

À ń bójú tó bá a ṣe ń tú àwọn ìwé tó dá lórí Bíbélì sí èdè tó lé ní àádọ́rin [70] jákèjádò orílẹ̀-èdè Mexico títí lọ dé orílẹ̀-èdè Panama. A máa ń tẹ àwọn ìtẹ̀jáde wa jáde ní àwọn èdè tó lé ní ọgọ́ta [60], a sì máa ń kó àwọn ìtẹ̀jáde wa tó wà ní èdè tó lé ní ọgọ́rin [80] lọ sí àwọn orílẹ̀ èdè tó lé ní mẹ́wàá.

Wa ìwé pẹlẹbẹ tó ń ṣàlàyé nípa ẹ̀ka ọ́fíìsì wa jáde.