Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

Ìsọfúnni Nípa Ọ́fíìsì àti Rírìn Yí Ká Ọgbà

Tayọ̀tayọ̀ la pè ẹ́ kó o wá rìn yí ká ọ́fíìsì wa àtàwọn ibi tá a ti ń tẹ̀wé. Wá ọ́fíìsì wa tó o lè lọ àti àsìkò tó o lè rìn yí ọgbà wa ká.

Madagascar

Vavolombelon’i Jehovah

Lot 1207 MC

Mandrosoa

105 IVATO

MADAGASCAR

+261 2022-44837

+261 3302-44837 ( Mobile)

Wíwo Ọgbà Wa Yíká

Monday sí Friday

7:30 àárọ̀ sí 11:00 àárọ̀ àti 1:00 ọ̀sán sí 4:00 ìrọ̀lẹ́

Ó máa gba wákàtí 1

Àwọn iṣẹ́ tí à ń ṣe níbẹ̀

À ń túmọ̀ àwọn ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì sí èdè Malagasy, Tankarana, Tandroy, àti Vezo. A máa ń gba ohùn sílẹ̀ a sì máa ń ṣe àwọn fídíò lédè Malagasy. À ń bójú tó iṣẹ́ àwọn ìjọ tó jẹ́ nǹkan bí ẹgbẹ̀ta [600]. À ń kó àwọn ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́ àti ìwé pẹlẹbẹ tó lé ní ọ̀kẹ́ mẹ́tàlá ààbọ̀ [270,000] àti àwọn ìwé ìròyìn tó lé ní ọgbọ̀n ọ̀kẹ́ [600,000] ránṣẹ́ lóṣooṣù síbi tá a ti nílò wọn.

Wa ìwé pẹlẹbẹ tó ń ṣàlàyé ẹ̀ka ọ́fíìsì wa jáde.