Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Ìsọfúnni Nípa Ọ́fíìsì àti Rírìn Yí Ká Ọgbà

Tayọ̀tayọ̀ la pè ẹ́ kó o wá rìn yí ká ọ́fíìsì wa àtàwọn ibi tá a ti ń tẹ̀wé. Wá ọ́fíìsì wa tó o lè lọ àti àsìkò tó o lè rìn yí ọgbà wa ká.

Korea

Sindumangok-ro 73, Gongdo-eup

Anseong-si, Gyeonggi-do

REPUBLIC OF KOREA

+82 31-690-0033

Wíwo Ọgbà Wa Yíká

Monday sí Friday

8:00 àárọ̀ sí 11:00 àárọ̀ àti 1:00 ọ̀sán sí 4:00 ìrọ̀lẹ́

Ó máa gba wákàtí 2

Àwọn iṣẹ́ tí à ń ṣe níbẹ̀

À ń tẹ àwọn ìwé ìròyìn tó jẹ́ mílíọ̀nù méjìdínlógún [18,000,000] ní èdè mẹ́fà lọ́dọọdún, a sì ń kó àwọn ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́ àti ìwé ìròyìn tí ìwọ̀n rẹ̀ tó àádọ́ta lé lẹ́gbẹ̀rin [850] tọ́ọ̀nù ránṣẹ́ lọ́dọọdún. À ń túmọ̀ àwọn ìwé wa sí èdè Korean àti Èdè Àwọn Adití Lọ́nà ti Korean. À ń ṣe àwọn fídíò tó wà ní Èdè Àwọn Adití Lọ́nà ti Korean.

Wa ìwé pẹlẹbẹ tó ń ṣàlàyé ẹ̀ka ọ́fíìsì wa jáde.