Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Ìsọfúnni Nípa Ọ́fíìsì àti Rírìn Yí Ká Ọgbà

Tayọ̀tayọ̀ la pè ẹ́ kó o wá rìn yí ká ọ́fíìsì wa àtàwọn ibi tá a ti ń tẹ̀wé. Wá ọ́fíìsì wa tó o lè lọ àti àsìkò tó o lè rìn yí ọgbà wa ká.

Kenya

Elgeyo Marakwet Rd

Kilimani area near Adams Arcade

NAIROBI

KENYA

+254 20-387-3211

+254 20-387-3212

+254 20-387-3213

Wíwo Ọgbà Wa Yíká

Monday sí Friday

8:00 àárọ̀ sí 11:00 àárọ̀ àti 1:00 ọ̀sán sí 4:00 ìrọ̀lẹ́

Ó máa gba ìṣẹ́jú 90

Àwọn iṣẹ́ tí à ń ṣe níbẹ̀

À ń bójú tó iṣẹ́ títúmọ̀ àwọn ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì sí èdè mẹ́wàá ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀, tó fi mọ́ Èdè Àwọn Adití Lọ́nà ti Kenyan. À ń gba ohùn sílẹ̀ a sì ń ṣe àwọn fídíò ní àwọn èdè ìbílẹ̀. A ń ṣètìlẹ́yìn fún iṣẹ́ àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà tó wà láwọn orílẹ̀-èdè tó wà nítòsí wa.

Wa ìwé pẹlẹbẹ tó ń ṣàlàyé ẹ̀ka ọ́fíìsì wa jáde.