Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

Ìsọfúnni Nípa Ọ́fíìsì àti Rírìn Yí Ká Ọgbà

Tayọ̀tayọ̀ la pè ẹ́ kó o wá rìn yí ká ọ́fíìsì wa àtàwọn ibi tá a ti ń tẹ̀wé. Wá ọ́fíìsì wa tó o lè lọ àti àsìkò tó o lè rìn yí ọgbà wa ká.

Japan

Watch Tower Bible and Tract Society

4-7-1 Nakashinden

EBINA CITY

KANAGAWA-PREF

243-0496

JAPAN

+81 46-233-0005

Wíwo Ọgbà Wa Yíká

Monday sí Friday

8:00 àárọ̀ sí 11:00 àárọ̀ àti 1:00 ọ̀sán sí 4:00 ìrọ̀lẹ́

Ó máa gba wákàtí 2

Àwọn iṣẹ́ tí à ń ṣe níbẹ̀

À ń tẹ́ Bíbélì, àwọn ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì àti àwọn ìwé pẹlẹbẹ tó lé ní mílíọ̀nù mẹ́ẹ̀ẹ́dógún, a sì ń tẹ àwọn ìwé ìròyìn tí lé ní ọgọ́rùn-ún [100] mílíọ̀nù lọ́dọọdún. À ń kó àwọn ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́ àtàwọn ìwé ìròyìn tí ìwọ̀n rẹ̀ tó ẹgbẹ̀rún márùn-ún ó lé ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀rin [5,700] tọ́ọ̀nù lọ́dọọdún ní àádọ́jọ [150] èdè.

Wa ìwé pẹlẹbẹ tó ń ṣàlàyé ẹ̀ka ọ́fíìsì wa jáde.