Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Ìsọfúnni Nípa Ọ́fíìsì àti Rírìn Yí Ká Ọgbà

Tayọ̀tayọ̀ la pè ẹ́ kó o wá rìn yí ká ọ́fíìsì wa àtàwọn ibi tá a ti ń tẹ̀wé. Wá ọ́fíìsì wa tó o lè lọ àti àsìkò tó o lè rìn yí ọgbà wa ká.

Italy

Congregazione Cristiana Dei Testimoni di Geova

Via della Bufalotta 1281

I-00138 ROME RM

ITALY

+39 06-872941

Wíwo Ọgbà Wa Yíká

Monday sí Friday

8:00 àárọ̀ sí 10:30 àárọ̀ àti 1:00 ọ̀sán sí 3:30 ọ̀sán

Ó máa gba ìṣẹ́jú 60

Àwọn iṣẹ́ tí à ń ṣe níbẹ̀

À ń túmọ̀ àwọn ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì sí èdè Italian àti Èdè Àwọn Adití Lọ́nà ti Italian. A máa ń gba ohùn sílẹ̀ a sì máa ń ṣe àwọn fídíò. A ń bójú tó iṣẹ́ àwọn ìjọ àtàwọn àwùjọ tó lé ní ẹgbẹ̀ẹ́dógún [3,000] tó wà lórílẹ̀-èdè Italy àtàwọn orílẹ̀-èdè míì.

Wa ìwé pẹlẹbẹ tó ń ṣàlàyé ẹ̀ka ọ́fíìsì wa jáde.