Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

Ìsọfúnni Nípa Ọ́fíìsì àti Rírìn Yí Ká Ọgbà

Tayọ̀tayọ̀ la pè ẹ́ kó o wá rìn yí ká ọ́fíìsì wa àtàwọn ibi tá a ti ń tẹ̀wé. Wá ọ́fíìsì wa tó o lè lọ àti àsìkò tó o lè rìn yí ọgbà wa ká.

Israel

Watchtower Association of Israel, RA

Shefer Street 23

6516604 TEL AVIV

ISRAEL

+972 3-5164039

Wíwo Ọgbà Wa Yíká

Sunday sí Thursday

8:00 àárọ̀ sí 11:00 àárọ̀ àti 1:00 ọ̀sán sí 4:00 ìrọ̀lẹ́

Ó máa gba ìṣẹ́jú 45 sí wákàtí kan

Àwọn iṣẹ́ tí à ń ṣe níbẹ̀

À ń túmọ̀ àwọn ìtẹ̀jáde tó dá lórí Bíbélì sí èdè Hébérù àti Èdè Àwọn Adití Lọ́nà ti Israeli. À ń ti àwọn ìjọ tó wà káàkiri orílẹ̀-èdè náà lẹ́yìn.

Wa ìwé pẹlẹbẹ tó ń ṣàlàyé nípa ẹ̀ka ọ́fíìsì wa jáde.