Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

Ìsọfúnni Nípa Ọ́fíìsì àti Rírìn Yí Ká Ọgbà

Tayọ̀tayọ̀ la pè ẹ́ kó o wá rìn yí ká ọ́fíìsì wa àtàwọn ibi tá a ti ń tẹ̀wé. Wá ọ́fíìsì wa tó o lè lọ àti àsìkò tó o lè rìn yí ọgbà wa ká.

Hungary

BUDAPEST

Kövirózsa u. 1.

H-1163

HUNGARY

+361 401-1100

Wíwo Ọgbà Wa Yíká

Monday sí Friday

10:00 àárọ̀ àti 3:00 ọ̀sán

Ó máa gba wákàtí kan àti ìṣẹ́jú 15

Àwọn iṣẹ́ tí à ń ṣe níbẹ̀

À ń bójú tó ìṣẹ́ àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ní ìjọ 294 tó wà ní orílẹ̀-èdè Hungary, a sì ń ṣètìlẹ́yìn fún àwọn ìjọ tó ń sọ èdè Hungarian ní orílẹ̀-èdè Slovakia àti Ukraine. À ń tú àwọn ìwé tó dá lórí Bíbélì sí èdè Hungarian àti Lovári. A tún máa ń gba ohùn sílẹ̀ fún àwọn ìtẹ̀jáde lédè Hungarian, a sì máa ń ṣe fídíò Èdè Àwọn Adití Lọ́nà ti Hungarian.

Wa ìwé pẹlẹbẹ tó ń ṣàlàyé nípa ẹ̀ka ọ́fíìsì wa jáde.