Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Ìsọfúnni Nípa Ọ́fíìsì àti Rírìn Yí Ká Ọgbà

Tayọ̀tayọ̀ la pè ẹ́ kó o wá rìn yí ká ọ́fíìsì wa àtàwọn ibi tá a ti ń tẹ̀wé. Wá ọ́fíìsì wa tó o lè lọ àti àsìkò tó o lè rìn yí ọgbà wa ká.

Ghana

Nungua Police Checkpoint

Hse. No. J 348/4

Tema Beach Road

Nungua

ACCRA

GHANA

+233 30-701-0110

+233 30-2712-456

+233 30-2712-457

+233 30-2712-458

Wíwo Ọgbà Wa Yíká

Monday sí Friday

8:00 àárọ̀ sí 11:00 àárọ̀ àti 1:00 ọ̀sán sí 4:00 ìrọ̀lẹ́

Ó máa gba wákàtí 1

Àwọn iṣẹ́ tí à ń ṣe níbẹ̀

À ń túmọ̀ àwọn ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì sí èdè Twi, Ewe, Ga, Dangme, Nzema, Frafra àti Dagaare. A tún máa ń gba ohùn sílẹ̀ a sì máa ń ṣe àwọn fídíò ní èdè Twi, Ewe àti Ga. A ń kọ́ ọgọ́ta [60] Gbọ̀ngàn Ìjọba ní ìpíndọ́gba lọ́dọọdún a sì ń kó ẹgbẹẹgbẹ̀rún tọ́ọ̀nù ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́ ránṣẹ́ sí ibi gbogbo lórílẹ̀-èdè Ghana.

Wa ìwé pẹlẹbẹ tó ń ṣàlàyé ẹ̀ka ọ́fíìsì wa jáde.