Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

Ìsọfúnni Nípa Ọ́fíìsì àti Rírìn Yí Ká Ọgbà

Tayọ̀tayọ̀ la pè ẹ́ kó o wá rìn yí ká ọ́fíìsì wa àtàwọn ibi tá a ti ń tẹ̀wé. Wá ọ́fíìsì wa tó o lè lọ àti àsìkò tó o lè rìn yí ọgbà wa ká.

Georgia

Aerodromis Dasahleba 13th Street, No. 10

BILISI, 0182

GEORGIA

+995 32-276-23-59

Wíwò Ọgbà Wa Yíká

Monday sí Friday

9:00 àárọ̀ sí 11:00 àárọ̀ sí 1:30 ọ̀sán sí 4:00 ìrọ̀lẹ́

Ó máa gba wákàtí kan

Jọ̀ọ́, pè kó o tó wá wò yíká ọgbà wa

Àwọn iṣẹ́ tí à ń ṣe níbẹ̀

Ẹ̀ka ọ́fíìsì yìí ló ń bójú to iṣẹ́ ìwáásù ní orílẹ̀-èdè Georgia àti Azerbaijan. Wọ́n tún ń bójú tó bí a ṣe ń tú àwọn ìwé tó dá lórí Bíbélì sí èdè Azerbaijani, Georgian, Kurdish Kurmanji (Caucasus àti Cyrillic) àti Mingrelian. Ẹ̀ká yìí náa ni wọ́n ti ń ṣé ìwé àwọn afọ́jú ní èdè Georgian.

Wa ìwé pẹlẹbẹ tó ń ṣàlàyé ẹ̀ka ọ́fíìsì wa jáde.