Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Ìsọfúnni Nípa Ọ́fíìsì àti Rírìn Yí Ká Ọgbà

Tayọ̀tayọ̀ la pè ẹ́ kó o wá rìn yí ká ọ́fíìsì wa àtàwọn ibi tá a ti ń tẹ̀wé. Wá ọ́fíìsì wa tó o lè lọ àti àsìkò tó o lè rìn yí ọgbà wa ká.

France

2 rue Saint-Hildevert

27400 LOUVIERS

FRANCE

+33 2-32-25-55-55

Wíwo Ọgbà Wa Yíká

Monday sí Friday

10:00 àárọ̀ àti 2:30 ọ̀sán

Ó máa gba wákàtí méjì

Àwọn iṣẹ́ tí à ń ṣe níbẹ̀

À ń túmọ̀ àwọn ìtẹ̀jáde tó dá lórí Bíbélì sí oríṣiríṣi èdè. À ń bójú tó iṣẹ́ àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà ní ilẹ̀ Faransé, Mauritius, Seychelles àti láwọn ilẹ̀ míì tí wọ́n ti ń sọ èdè Faransé (bí àpẹẹrẹ, French Guiana, Guadeloupe, Martinique, Mayotte, Réunion, Saint Barthélemy, Saint Martin àti Saint Pierre and Miquelon).

Wa ìwé pẹlẹbẹ tó ń ṣàlàyé nípa ẹ̀ka ọ́fíìsì wa jáde.