Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Ìsọfúnni Nípa Ọ́fíìsì àti Rírìn Yí Ká Ọgbà

Tayọ̀tayọ̀ la pè ẹ́ kó o wá rìn yí ká ọ́fíìsì wa àtàwọn ibi tá a ti ń tẹ̀wé. Wá ọ́fíìsì wa tó o lè lọ àti àsìkò tó o lè rìn yí ọgbà wa ká.

Finland

Puutarhatie 60

FI-01300 VANTAA

FINLAND

+358 9-825-885

Wíwo Ọgbà Wa Yíká

Monday sí Friday

9:00 àárọ̀, 10:30 àárọ̀, 1:30 ọ̀sán àti 3:00 ọ̀sán

Ó máa gba wákàtí kan

Àwọn iṣẹ́ tí à ń ṣe níbẹ̀

Ẹ̀ka ọ́fíìsì wa lórílẹ̀-èdè Finland ń bójú tó iṣẹ́ àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà tó tó ẹgbẹ̀rún mẹ́rìnlélọ́gbọ̀n [34,000] tí wọ́n wà lórílẹ̀-èdè Belarus, Estonia, Finland, Latvia àti Lithuania. Ẹ̀ka yìí ń rí sí i pé a túmọ̀ àwọn ìwé tó dá lórí Bíbélì sí èdè mẹ́fà táwọn èèyàn ń fẹnu sọ àti èdè adití mẹ́rin.

Wa ìwé pẹlẹbẹ tó ń ṣàlàyé nípa ẹ̀ka ọ́fíìsì wa jáde.