Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Ìsọfúnni Nípa Ọ́fíìsì àti Rírìn Yí Ká Ọgbà

Tayọ̀tayọ̀ la pè ẹ́ kó o wá rìn yí ká ọ́fíìsì wa àtàwọn ibi tá a ti ń tẹ̀wé. Wá ọ́fíìsì wa tó o lè lọ àti àsìkò tó o lè rìn yí ọgbà wa ká.

Dominican Republic

Autopista San Isidro #100

(Al lado de Coral Mall, Frente a Savica)

SANTO DOMINGO ESTE

DOMINICAN REPUBLIC

+1 809-595-4007

Wíwo Ọgbà Wa Yíká

Monday sí Friday

8:00 àárọ̀ sí 11:00 àárọ̀ àti 1:00 ọ̀sán sí 4:00 ìrọ̀lẹ́

Ó máa gba wákàtí 1

Àwọn iṣẹ́ tí à ń ṣe níbẹ̀

À ń bójú tó iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì tí àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà ń ṣe lórílẹ̀-èdè Dominican Republic. A máa ń sọ ìtàn àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà orílẹ̀-èdè yìí fún àwọn èèyàn tí wọ́n wá wo ọgbà wa.

Wa ìwé pẹlẹbẹ tó ń ṣàlàyé ẹ̀ka ọ́fíìsì wa jáde.