Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

Ìsọfúnni Nípa Ọ́fíìsì àti Rírìn Yí Ká Ọgbà

Tayọ̀tayọ̀ la pè ẹ́ kó o wá rìn yí ká ọ́fíìsì wa àtàwọn ibi tá a ti ń tẹ̀wé. Wá ọ́fíìsì wa tó o lè lọ àti àsìkò tó o lè rìn yí ọgbà wa ká.

Denmark

Stenhusvej 28

DK-4300 HOLBAEK

DENMARK

+45 59-45-60-00

Wíwo Ọgbà Wa Yíká

Monday sí Friday

9:00 àárọ̀, 10:30 àárọ̀, 1:30 ọ̀sán, àti 3:00 ọ̀sán.

Ó máa gba ìṣẹ́jú 90

Àwọn iṣẹ́ tí à ń ṣe níbẹ̀

Ẹ̀ka ọ́fíìsì wa tó wà ní Scandinavia ń bójú tó iṣẹ́ ìwàásù àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà tó tó ẹgbẹ̀rún lọ́nà àádọ́ta [50,000] tí wọ́n wà ní orílẹ̀-èdè Denmark, Iceland, Norway, Sweden àti àwọn erékùṣù àwọn Faeroe àti Greenland. Wọ́n tún ń bójú tó iṣẹ́ ìtumọ̀ àwọn ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì sí èdè mẹ́fà táwọ̀n èèyàn ń sọ àti èdè àwọn adití mẹ́ta, wọ́n sì ń ṣe àwọn ìtẹ̀jáde tá a gba ohùn ẹ̀ sílẹ̀ àti fídíò ní ọ̀pọ̀ àwọn èdè náà.

Wa ìwé pẹlẹbẹ tó ń ṣàlàyé ẹ̀ka ọ́fíìsì wa jáde.