Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Ìsọfúnni Nípa Ọ́fíìsì àti Rírìn Yí Ká Ọgbà

Tayọ̀tayọ̀ la pè ẹ́ kó o wá rìn yí ká ọ́fíìsì wa àtàwọn ibi tá a ti ń tẹ̀wé. Wá ọ́fíìsì wa tó o lè lọ àti àsìkò tó o lè rìn yí ọgbà wa ká.

Congo (Kinshasa)

75, 13e Rue, Q. Industriel

LIMETE

KINSHASA

DEMOCRATIC REPUBLIC OF THE CONGO

+243 81-555-1000

+243 99-818-9791

Wíwo Ọgbà Wa Yíká

Monday sí Friday

9:00 àárọ̀ sí 10:30 àárọ̀ àti 1:30 ọ̀sán sí 3:00 ọ̀sán

Ó máa gba wákàtí kan

Àwọn iṣẹ́ tí à ń ṣe níbẹ̀

À ń túmọ̀ ìwé ìròyìn Ilé Ìṣọ́ sí èdè mẹ́jọ, a sì ń túmọ̀ àwọn ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́ míì sí ọgbọ̀n [30] èdè. À ń kó àwọn ìtẹ̀jáde tó tó ẹgbẹ̀rún kan ó lé ọgọ́rùn ún mẹ́jọ [1,800] tọ́ọ̀nù ránṣẹ́ sí 3,746 ìjọ jákèjádò orílẹ̀-èdè Congo (Kinshasa).

Wa ìwé pẹlẹbẹ tó ń ṣàlàyé nípa ẹ̀ka ọ́fíìsì wa jáde.