Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

Ìsọfúnni Nípa Ọ́fíìsì àti Rírìn Yí Ká Ọgbà

Tayọ̀tayọ̀ la pè ẹ́ kó o wá rìn yí ká ọ́fíìsì wa àtàwọn ibi tá a ti ń tẹ̀wé. Wá ọ́fíìsì wa tó o lè lọ àti àsìkò tó o lè rìn yí ọgbà wa ká.

Chile

Ave Concha y Toro 3456

PUENTE ALTO

CHILE

+56 2-428-2600

+56 2-428-2609 (Fax)

Wíwo Ọgbà Wa Yíká

Monday sí Friday

8:30 àárọ̀, 9:30 àárọ̀, 10:30 àárọ̀, 1:30 ọ̀sán, 2:30 ọ̀sán, 3:30 ọ̀sán.

Ó máa gba wákàtí 1

Àwọn iṣẹ́ tí à ń ṣe níbẹ̀

À ń bójú tó iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ tí àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà ń ṣe lórílẹ̀-èdè Chile. À ń kó àwọn ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́ ránṣẹ́ sí àwọn ìjọ tó lé ní ẹgbẹ̀rin [800].

Wa ìwé pẹlẹbẹ tó ń ṣàlàyé ẹ̀ka ọ́fíìsì wa jáde.