Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Ìsọfúnni Nípa Ọ́fíìsì àti Rírìn Yí Ká Ọgbà

Tayọ̀tayọ̀ la pè ẹ́ kó o wá rìn yí ká ọ́fíìsì wa àtàwọn ibi tá a ti ń tẹ̀wé. Wá ọ́fíìsì wa tó o lè lọ àti àsìkò tó o lè rìn yí ọgbà wa ká.

Canada

13893 Highway 7

GEORGETOWN ON L7G 4S4

CANADA

+1 905-873-4100

Wíwo Ọgbà Wa Yíká

Monday sí Friday

8:00 àárọ̀ sí 10:00 àárọ̀ àti 1:00 ọ̀sán sí 3:00 ọ̀sán

Ó máa gba wákàtí 2

Àwọn iṣẹ́ tí à ń ṣe níbẹ̀

À ń tẹ àwọn ìwé ìròyìn tó lé ní ọ̀tàlérúgba ó dín márùn-ún mílíọ̀nù [255,000,000] lọ́dọọdún. A sì máa ń kó àwọn ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́ tó lé ní ẹgbẹ̀rún mẹ́fà [6,000] tọ́ọ̀nù ní nǹkan bí ọ̀ọ́dúnrún èdè [300] ránṣẹ́ lọ́dọọdún sí ibi tí wọ́n ti nílò rẹ̀.

Wa ìwé pẹlẹbẹ tó ń ṣàlàyé ẹ̀ka ọ́fíìsì wa jáde.