Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

Ìsọfúnni Nípa Ọ́fíìsì àti Rírìn Yí Ká Ọgbà

Tayọ̀tayọ̀ la pè ẹ́ kó o wá rìn yí ká ọ́fíìsì wa àtàwọn ibi tá a ti ń tẹ̀wé. Wá ọ́fíìsì wa tó o lè lọ àti àsìkò tó o lè rìn yí ọgbà wa ká.

Cameroon

Les Témoins de Jéhovah du Cameroun

Ancienne Route SONEL

Bonamikano, Bonabéri,

DOUALA

CAMEROON

+237 3339-0250

+237 3339-2101

Wíwo Ọgbà Wa Yíká

Wednesday àti Friday

2:00 ọ̀sán sí 4:30 ìrọ̀lẹ́

Ó máa gba ìṣẹ́jú 30

Àwọn iṣẹ́ tí à ń ṣe níbẹ̀

À ń bójú tó iṣẹ́ àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà tó lé ní ọ̀kẹ́ méjì [40,000] tó wà ní orílẹ̀-èdè Cameroon, Gabon àti Equatorial Guinea. À ń kó àwọn ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́ ránṣẹ́ sí orílẹ̀-èdè márùn-ún nílẹ̀ Áfíríkà.

Wa ìwé pẹlẹbẹ tó ń ṣàlàyé ẹ̀ka ọ́fíìsì wa jáde.