Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

Ìsọfúnni Nípa Ọ́fíìsì àti Rírìn Yí Ká Ọgbà

Tayọ̀tayọ̀ la pè ẹ́ kó o wá rìn yí ká ọ́fíìsì wa àtàwọn ibi tá a ti ń tẹ̀wé. Wá ọ́fíìsì wa tó o lè lọ àti àsìkò tó o lè rìn yí ọgbà wa ká.

Burundi

Les Témoins de Jéhovah

Uprona Boulevard

Corner of Muyinga Ave., Rohero II

BUJUMBURA

BURUNDI

+257 2224-1110

+257 2224-5564

+257 2224-8112

Wíwo Ọgbà Wa Yíká

Monday sí Friday

8:00 àárọ̀ sí 11:00 àárọ̀ àti 1:00 ọ̀sán sí 4:00 ìrọ̀lẹ́

Ó máa gba wákàtí 1

Àwọn iṣẹ́ tí à ń ṣe níbẹ̀

À ń túmọ̀ àwọn ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì, à ń ka àwọn ìtẹ̀jáde ní èdè Kirundi, a sì ń gbohùn wọn sílẹ̀. À ń kó àwọn ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́ ránṣẹ́ sí àwọn ìjọ àti àwùjọ tó lé ní okòó-dín-lọ́ọ̀ọ́dúnrún [280].

Wa ìwé pẹlẹbẹ tó ń ṣàlàyé ẹ̀ka ọ́fíìsì wa jáde.