Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

Ìsọfúnni Nípa Ọ́fíìsì àti Rírìn Yí Ká Ọgbà

Tayọ̀tayọ̀ la pè ẹ́ kó o wá rìn yí ká ọ́fíìsì wa àtàwọn ibi tá a ti ń tẹ̀wé. Wá ọ́fíìsì wa tó o lè lọ àti àsìkò tó o lè rìn yí ọgbà wa ká.

Britain

Watch Tower

The Ridgeway

LONDON

NW7 1RN

ENGLAND

+44 20-8906-2211

Wíwo Ọgbà Wa Yíká

Monday sí Friday

9:45 àárọ̀; 1:15 ọ̀sán; 3:00 ọ̀sán.

Ó máa gba ìṣẹ́jú 90

Àwọn iṣẹ́ tí à ń ṣe níbẹ̀

À ń tẹ àwọn ìwé ìròyìn àti ìwé pẹlẹbẹ tó lé ní igba [200] mílíọ̀nù lọ́dọọdún, a sì ń kó wọn ránṣẹ́ sí àwọn orílẹ̀-èdè tó jẹ́ ọgọ́rùn-ún [100] kárí ayé. A máa ń ṣàfihàn àwọn ohun tá a ti lò látijọ́ tó ń sọ nípa iṣẹ́ àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà nílẹ̀ Britain fún àwọn tó wá wo ọgbà wa.

Wa ìwé pẹlẹbẹ tó ń ṣàlàyé ẹ̀ka ọ́fíìsì wa jáde.